Awọn asọbode yinbọn pa Rilwan l'Ogun IROYIN OJUTOLE May 04, 2020 Beeyan ba jẹ ori ahun omi yoo bọ loju ẹ to ba debi ti ibọn awọn asọbode, ti wọn pe ni kọsitọọmu ti yinpa pa ọdọmọkunrin, ẹni ọdun mẹẹẹdogun... KAA SIWAJU
O ye kijoba ju Dangote sewon ni, Satguru Maharaj lo so bee IROYIN OJUTOLE December 28, 2018 Taofik Afolabi O lori ijo ‘One Love Family’, Satguru Mahara J Ji, ti so o di mimo pe ahamo awon olopaa lo ye ki baba olowo oril... KAA SIWAJU
ALAHU AKBAR:ORUKO OLORUN JADE NINU ODO AMULE 'ILORIN IROYIN OJUTOLE October 26, 2018O hun iyanu lo sele niluu kan toruko re n je Amule, niluu Ilorin, nipinle Kwara, lojiji lawon ara ilu yii ri oruko Olorun to n je 'Alahu... KAA SIWAJU
AGBALAGBA RADARADA REE O, OKUNRIN YII SI FUN OMO E LOYUN IROYIN OJUTOLE October 04, 2018 E wo okunrin yii daadaa, e wo o ke e tun un wo, omo e lo fun loyun niluu Edo, owo awon olopaa si ti te e bayii. Gege bi a se gbo, lati o... KAA SIWAJU
HA: FUNKE, OMO DOYIN AGBAMU ONISOWO KWARA KU, KANSA LO PA A IROYIN OJUTOLE September 28, 2018 1 n jo , Ninu ibanuje lawon oloselu ipinle Kwara, paapaa awon omo egbe oselu PDP wa bayii lori iku ojiji to pa okan lara won.... KAA SIWAJU
IKUNLE ABIYAMO O:BI EEYAN MEJIDINLOGUN SE KU SINU IJAMBA OKO LONA IGEDE- EKITI REE IROYIN OJUTOLE September 26, 2018 Ariwo ikunle abiyamo lo gba enu awon eeyan nigba ti won ri i bi eeyan mejidinlogun se pare sinu ijamba moto to sele lona Awo si Igede-Ekiti... KAA SIWAJU