Wọn ni Tunde Lẹmọ di ṣẹrubawọn fawọn oludije gomina ipinlẹ Ogun yooku IROYIN OJUTOLE March 01, 2026 Ki i ṣe tuntun mọ pe Tunde Lẹmọ, ẹni to ti figba kan jẹ igbakeji ọga agba banki nilẹ wa, ti jade lati dupo fun ipo gomina ninu i... KAA SIWAJU
Adron Group Congratulates Ogun State At 50, Salutes Legacy of Progress IROYIN OJUTOLE February 03, 2026 The Board of Directors, Management, and staff of Adron Group heartily congratulate His Excellency, Prince Dapo Abiodun, MFR, CON... KAA SIWAJU
Alaimọkan lo n sọ pe ayẹyẹ ọjọọbi Anọbi ko ṣe pataki- Al-Khaleefah Ọlọrunṣẹyẹ. IROYIN OJUTOLE November 29, 2025 Fadilat Sheikh Al-Khaleefah Abdul Quadri Ishọla Ọlọrunṣẹyẹ, to jẹ oludasilẹ ileewe JAMHYAT NUUR SOMODANY AL-ISLAMY FOUNDATION... KAA SIWAJU
Eyi lohun ti Iyayẹmi Ẹlẹbuibọn sọ nipa obinrin to n fi inu meji ba ọkọ lo IROYIN OJUTOLE October 24, 2025 Àràbà Awo ilẹ Oṣogbo. Araba Ifayẹmi Ẹlẹbuibọn, ti ṣalaye ewu to wa fun iyawo ile ti ko jẹ oloootọ si ọkọ... KAA SIWAJU
O tan:Alaga APC tẹlẹ ni Enugu atawọn ọpọ eeyan darapọ mọ ADC IROYIN OJUTOLE October 23, 2025 A fi bii awọro lọrọ naa jẹ nipinlẹ Enugu, nigba ti alaga fẹgbẹ oṣelu APC tẹlẹ, Ọgbẹni A C Udeh ati olori awọn obinrin,Lolo Nwakw... KAA SIWAJU
Bi won ṣe dana sun ọfiisi ijọba ni Ekiti lọwọ oṣelu ninu-ADC IROYIN OJUTOLE October 22, 2025 Ẹgbẹ oṣelu Afican Democratic Congress, ADC, ti fi aidunnu wọn han lori ijanba ina kan to waye ni ọfiisi ijọba iyẹn sẹkiteriati, ... KAA SIWAJU
Gọngọ sọ nibi ayẹyẹ ọjọọbi Sẹrifat iyawo Rauf Arégbẹṣọla l'Ekoo IROYIN OJUTOLE September 27, 2025 Rauf Arẹgbẹṣọla ṣayẹ... KAA SIWAJU
Arẹgbẹṣola ro awon omo egbe ADC lOsun lati gba kaadi idibo IROYIN OJUTOLE September 08, 2025 Pitimu ni inu gbọgan kan ti Ọgbẹni Rauf Aregbesola ti ma n ṣe ìpàdé ẹgbẹ Ọmọluab... KAA SIWAJU
Yoruba lo yẹ ko jẹ aṣaaju nipa fila ati gele lagbaaye- Alake tilẹ Ẹgba IROYIN OJUTOLE August 27, 2025 Alake tilẹ Ẹgba, Ọba Adedọtun Arẹmu Gbadebọ, ti ṣapejuwe Yoruba gẹgẹ bii aṣiwaju laarin awọn ẹya gbogbo kaakiri agbaye, paapaa, ... KAA SIWAJU
Erongba wa ni lati ṣaaju awọn ọmọ orileede yii wọ ilẹ ileri lọdun 2027- Arẹgbẹṣola IROYIN OJUTOLE August 23, 2025 Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla, akọwe fẹgbẹ ADC lapapọ ti sọ pe erongba wọn... KAA SIWAJU
Iwa ti ko bojumu ni idukoko ti wọn ṣe fun Arẹgbẹṣla-ADC Ogun IROYIN OJUTOLE August 19, 2025 Ẹgbẹ oṣelu ADC, ẹka ipinlẹ Ogun ti tako bawọn oloṣelu kan ṣe n dunkoko mọ Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla, akọwe ẹgbẹ naa lapapọ, wọn ni ... KAA SIWAJU
Aṣiiri bawọn kan ṣe fẹẹ gbẹmi Arẹgbẹṣọla ti tu o IROYIN OJUTOLE August 17, 2025 Ẹgbẹ ilọsiwaju Ọmọluabi iyẹn Ọmọluabi Progresive ti pariwo sita pe gbogbo ọna lawọn kan fi n wa lati gba ẹmi akọwe tuntun fẹgbẹ ... KAA SIWAJU
KÀYÉEFÌ ŃLÁ : ÌJOBA ÌPÍNLÈ OGUN KỌ JALÈ LÀTI JẸ KÍ SOLOMON OSHO ṢE ÌPOLONGO ÌBÒ NÍ ÌLÚ REMO. IROYIN OJUTOLE August 14, 2025 Nise ni gbogbo awon to wa niwájú ilé ìwé girama tí ilu Remo n kọ haa!,Tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ sì lanu silẹ lai ma lè padé nígbà tí wọ́n rí bí oriṣii... KAA SIWAJU