Ariwo ikunle abiyamo lo gba enu awon eeyan nigba ti won ri i bi eeyan mejidinlogun se pare sinu ijamba moto to sele lona Awo si Igede-Ekiti laaro yii, lojuese lawon eeyan naa gbemi min.
Moto akero ti oda ara re je funfun ti nomba e je EKY 978XJ lawon eeyan naa wo, bo se de agbegbe yii laa gbo pe o loo ko lu moto akero Toyoya ti wahala nla si sele. Lati ilu Eko la gbo pe oko akero tawon eeyan ku ninu e yii ti gbera, Abuja ni won so pe o n lo.
Nibi tijamba yii lagbara de, ori awon kan ninu awon to kagbako ijamba yii ge. Ki Olorun ba wa dawo aburu duro,ko si fori awon to ku
No comments:
Post a Comment