IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday 26 October 2018

ALAHU AKBAR:ORUKO OLORUN JADE NINU ODO AMULE 'ILORIN

Ohun iyanu lo sele niluu kan toruko re n je Amule, niluu Ilorin, nipinle Kwara, lojiji lawon ara ilu yii ri oruko Olorun to n je 'Alahu' to jade lori odo yii. Awon ti won ji lo sodo la gbo pe won ri ohun iyanu yii, ni won ba mu iroyin ohun ti won ri yii to awo to wa nile lo.

Ariwo 'Alahu Akbar'  lo gba enu gbogbo awon ti won ri ise iyanu nla yii. 


No comments:

Post a Comment

Adbox