IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 7 January 2025

GBAJUGBAJA ONiROYIN, OLAIDE GOLD DI IYA IROYIN ILU MEIRAN, NIPINLE EKO



Olaide Aderonke Gold ti gbogbo Ololufe e mo si Olaide Gold di IYA IROYIN fun ilu Meiran ni tile toko ati agbegbe e. Yiniyini ki eni le se imiran, lo mu Baba wa Kabiyesi Alaiyeluwa Oba Awoyemi Adisa Joro , Onimeiran ti ilu Meiran fi oye Iya Iroyin da Ogbontarigi Akoroyin Olaide Aderonke aya Gold lola. Eyiti ao se iwuye e ni ojo kerinlelogun osu kini Odun yi(24/01/2025), ni Afin Onimeran ni Ilu Meiran ni Ipinle Eko, nideedee agogo mesan owuro. Gbogbo iko Akede Isokan Yoruba gbaladura pe Ojo na yio koo, Ao jo peju se ni o. Lagbara Edumare o.

No comments:

Post a Comment

Adbox