IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 4 November 2020

Gbajugbaja Olorin Islam, Alaaja Rodiat Ayinke Adeboye lo n sojoobi lonii

Okan pataki ninu awon omo orile-ede yii to n fi ebun ti Olorun fun un fi gbe Naijiria ga loke-okun ni Alaaja Rodiat Ayinke Adeboye ti gbogbo aye mo si Alariya Dublin.
Onii lobinrin arewa naa sayeye ojoobi e, gbogbo awon ololufe e kari aye ni won ti n ki I fun ojoobi ohun.

Awa naa ba Alariya Dublin Hello Olohun dupe fun ojoobi e yii, opo odun ni won too se late.

No comments:

Post a Comment

Adbox