IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 9 November 2020

Alaga Ijoba Ibile Idagbasoke Ifelodun, Onarebu Fatai Shuaib Ajidagba tun derin-in peeke awon araalu

Eyi nibi alaga idagbasoke ijoba ibile Ifelodun, Onarebu Fatai Shuaib Ajidagba Ajifat se tun derin-in peeke awon araalu ninu osu kokanla yii. Ero amomitutu nla, ero amunawa ati owo nla lo fi ro won lagbara. 

Ariwo tawon araalu n pa ni pe alaaanu wa ni Ajifat Oloronbo

No comments:

Post a Comment

Adbox