Okunrin omo bibi ilu Egba yii wa lara awon gbajumo to saaju fun iwode endsars.
Sa o, Freaky Freaky bi awon kan se tun n pe osere naa ti fibinu soro, ninu oro e to gbe ero alatagba e lo ti so bayii pe 'Bawo ni ko ba se wu mi ki iya egbeta odun je awon to n fi iya je awon mekunnu lorile-ede yii.
Bi Macaroni se soro yii lawon ololufe e so pe eyi to so naa ase ti gun in.
Fawon ti ko ba ranti, Mr.Macaroni wa lara awon gbajumo tijoba apapo gbe lo sile-ejo fun sise onigbowo fun iwode endsars.
No comments:
Post a Comment