IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 19 April 2020

O ma ṣe o: Ara Ogun Majek, agba-ọjẹ onitiata ko ya o

Inu adura nla lawọn ẹbi agba-ọjẹ osere tiata Yoruba nni, Alagba Gbolagade Akeem Akinpẹlu ti gbogbo aye mọ si Ogun Majek wa bayii, aisan nla kan lo n ṣe baba naa. Lati bii ọjọ meloo kan la gbọ pe aisan nla ọhun ti n ba baba yii finra ti awọn oṣere ẹgbẹ ẹ si n ran an lọwọ, ṣugbọn nibi ti nnkan de duro bayii, Ogun Majek nilo iranlọwọ awọn araalu fun itọju to peye. Ẹnikẹni to ba fẹẹ ran baba yii lọwọ, ẹ fi ohun ti ẹ fẹẹ fun un sinu akanti yi
i: 0125019443 Akinpelu Akeem Abidemi GT bank. .

No comments:

Post a Comment

Adbox