IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday, 1 October 2018

ONI LOJOOBI GBAJUMO OLORIN, SEGUN AYOMIKUN,EJE KA KI BETTER MAN KU ORIIRE

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki eeyan wa daadaa, gbajugbaja olorin emi ati juju to fi ilu London sebugbe, Segun Ayomikun ti gbogbo aye mo si Better Man.

Adura wa ni pe ki omo olojoobi sopo odun laye ninu ola, alaaafia ara ati alubarika to po. Hapi Batide to sa.

No comments:

Post a Comment

Adbox