Nigba to n soro nipa ami-eye yii, Ayangbajumo ni 'Mi o ni i lokan pe mo ma gba awoodu nibi loni-in, ohun to wa lokan ni pe ki n lulu fawon eeyan, sugbon e jo mi loju pelu ami-eye.
Mo dupe lowo awon eleto ami-eye yii, mo dupe lowo Queen New Jersey, mo dupe lowo Afidipotemole, mo dupe lowo Olantech Promotion, mo dupe lowo Luku Jazz, mo dupe lowo Onfoloke.
Nipari, mo fi awoodu yi sori gbogbo awon ololufe mi, awon ebi atawon afenifere',
No comments:
Post a Comment