IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday 18 September 2018

'NITORI OMU MI TO TOBI DAADAA LAWON OKUNRIN SE FERAN MI LORI ERO AYELUJARA'

Omobirin kan to pe oruko ara re ni Jesus Babe lori eka ayelujara ti won n pe ni 'Istagram' ti so pe nitori omu oun to tobi daadaa lawon okunrin se feran oun lori ero ayelujara.
Alaye to se e ni pe pelu bi oun ki i se  ko awon oro to dara lori eka ayelujara yii, sibe awon eeyan to le ni egberun-un lona ogun ni won feran oun, o si da oun loju doba pe nitori oyan oun to tobi daadaa lo je ki won maa n te le oun lori 'instagram' yii.


No comments:

Post a Comment

Adbox