Gbogbo awon eeyan to gbo nipa oriire nla to sele si gbajumo osere tiata, to tun je ajafetoo omo eniyan, iyen Abayomi Fabiyi. Lati ojo meloo kan ti osere nla tawon kan tun mo si Araba ti kede Ile olowo nla to sese pari siluu Abeokuta, nipinle Ogun, lawon eeyan ti n ba okunrin dupe fun pore nla ohun.
Bi awon osere egbe e se ki i ku oriire, bee lawon ololufe kari aye n ba a dupe, won ni Araba nla lokunrin naa loooto.
Bakan naa la gbo pe Inu osu karun-un odun yii layeye sisi Ile naa yoo waye, nibi tawon eeyan pataki lawujo yoo ti I wa a ba Yomi sile awosifila naa.
No comments:
Post a Comment