IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday 14 June 2024

Ope o: Omo Ayangbajumo, bi Ibeji l'Amerika


Inu ayo ati idunnu nla ni gbajumo obinrin onllu nni, Queen Eniola Abiọdun Lias ti gbogbo aye mo si Queen Ayangbajumo wa bayii, omo e lo bi ibeji lantilanti sorileede Amerika. Ojo Abameta, Satide to koja yii ni nnkan ayo yii sele nile awon Ayangbajumo. 


Ileewosan kan toruko e n je Beth Israel hospital Newark to wa niluu  New Jersey jersey,  lorileede Amerika lomo Ayangbajumo bi awon Ibeji ohun si.

 A gbo lalaafia ni iya ikoko atawon Ibeji wa. Ninu oro Ayangbajumo lo ti so pe 'Mo dupe lowo Olorun fun oore nla to se fun mi, omo mi lo bibeji, e pe mi ni iya-iya Ibeji, emi gan-an ni olope' o: Omo  Ayangbajumo, bi Ibeji l'Amerika

Inu ayo ati idunnu nla ni gbajumo obinrin onllu nni, Queen Eniola Abiọdun Lias ti gbogbo aye mo si Queen Ayangbajumo wa bayii, omo e lo bi ibeji lantilanti sorileede Amerika. Ojo Abameta, Satide to koja yii ni nnkan ayo yii sele nile awon Ayangbajumo. 


Ileewosan kan toruko e n je Beth Israel hospital Newark to wa niluu  New Jersey jersey,  lorileede Amerika lomo Ayangbajumo bi awon Ibeji ohun si.

 A gbo lalaafia ni iya ikoko atawon Ibeji wa. Ninu oro Ayangbajumo lo ti so pe 'Mo dupe lowo Olorun fun oore nla to se fun mi, omo mi lo bibeji, e pe mi ni iya-iya Ibeji, emi gan-an ni olope'

No comments:

Post a Comment

Adbox