Bi nnkan se lo yii, boya ni ondije ipo gomina ninu egbe oselu APC l'Ekoo, Ogbeni Jide Sanwo-Olu, ko ni i feyin gomina ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode janle bayii. Ohun ti Ojutole gbo pe Sanwo-Olu lon saaju ninu eto idibo abele egbe naa to n lo lowo. Die ninu awon esin idibo to ti jade ree o
LG Ward D, Emmanuel Primary School.
Result:
No comments:
Post a Comment