Awon omo egbe oselu PDP nipinle Eko ti dibo yan Ogbeni Jimi Agbaje gege bii oludije funpo gomina ipinle Eko ninu egbe won. Oni-in, ojo Eti, Fraide nibo naa waye. Ibo egberun-un kan ati ogorun-un ni Agbaje fi lu alatako e, Deji Doherty.
Pelu ohun to sele yii, Agbaje pelu Babajide Sanwo-Olu tegbe oselu APC ni won yoo tun jo dunpo gomina Eko lodun to n bo.
Te o ba gbagbe, Jimi Agbaje yii kan naa lo koju gomina to wa lori aleefa bayii, Ogbeni Akiwunmi lodun 2015, sugbon Ambode lo wole
.
No comments:
Post a Comment