IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 5 October 2018

SHINA PELLER LEGBE APC DIBO YAN LATI DUNPO ASOJU AWON EEYAN ITESIWAJU,ISEYIN,KAJOLA ATI IWAJOWA NILE IGBIMO ASOJU-SOFIN L;ABUJA

Onisowo pataki nni, Shina Peller, lawon omo egbe oselu APC lekun idibo Itesiwaju, Kajola,Iseyin ati Iwajowa nipinle Oyo  dibo yan gege bii eni ti yoo dunpo loruko egbe naa lati loo soju awon eeyan e nile igbimo asoju-sofin l'Abuja lodun to n bo.

Ibo repete lawon eeyan naa fi yan Peller tawon ore e maa n pe ni Olowo Idan gege bii oludije ninu egbe won. 

Ninu oro e lo ti dupe lowo gomina ipinle Oyo, Senato Abiola Ajimobi, awon agba egbe APC atawon omo egbe gbogbo ti won dibo yan an.

No comments:

Post a Comment

Adbox