IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 3 October 2018

IJA PARI: AMBODE KI SANWO-OLU KU ORIIRE, O TUN SELERI ATILEYIN FUN UN

Leyin tigbimo to se kokaari eto idibo abele gomina egbe oselu APC nipinle Eko ti kede pe Ogbeni Jide Sanwo-Olu lawon omo egbe naa dibo fun gege bii eni ti soju egbe naa ninu ibo gbogbogboo odun to n bo, Gomina ipinle Eko, Ogbeni Akinwumi Ambode, ti ki alatako e yii ku oriire.

Ninu oro ku oriire ti Ambode fi sowo si Sanwo-Olu,  lo ti ku oriire bo se jawe olubori, bee lo so pe oun yoo satileyin fegbe APC lati ri i pe egbe awon nipo gomina naa tun bo si lowo ninu ibo odun to n bo.

Ana, ojo Isegun, Tusde nibo abele egbe APC lati yan eni ti yoo dunpo gomina loruko egbe naa waye laarin Ambode ati Sanwo-Olu, tawon omo egbe si fi ibo roburobu gbe Sanwo-Olu, ti won tun pe ni Sanwo-Eko wole
.  

No comments:

Post a Comment

Adbox