IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 3 October 2018

E WO ALAAJA KEMI OLOJO, IYALAJE GBOGBO SAUDI NIYEN

Okan pataki ninu awon omo orile-ede yii, ti won n gboruko Naijiria ga loke okun ni Alaaja Oluwakemi Olojo, ti gbogbo aye mo si Iyalaje Saudi. Onisowo pataki, ti ko fi jibiti tabi ogbon alumokoroyi ku ise re ni Iyalaje n se, ilu Saudi lo ti n sowo, bee ni ko kere ninu ise adinni, musulumi ododo ti ki i fi wakati marun-un sere ni Alaaja Kemi n se.


Beeyan ba n wa ojulowo jalamia, iborun to je oju ni gbese, awon aso alaranbara tawon alafe n wo lo si ibise tabi ode ariya. Bo si je awon eso ara ni,gbogbo e lo wa nileetaja Iyalaje. 

Beeyan ba de ileese Alaaja toruko re n je 'Kemobash Fashion World' , onitohun-un yoo mo pe ojulowo onisowo ti Olorun gba fun ni mama yii. 

Ohun to je ki ileetaja 'Kemobash Fashion World' yato sawon ileetaja yooku, to si mu won gba ipo kin in ni ni pe otito inu, ifarada ati mimo riri awon onibaara won lo se pataki ju lookan aya won, won o ki i fawon onibaara won sere rara, bee lawon oja won roju daadaa, won o ki i je ere ajepajude ni tiwon.

Enikeni to ba wa ri Alaaja Oluwakemi Olojo, e so fun won Ojutole so pe apamowo owo atajeere oja,  alubarika repete ninu ise won lola Onise Nla. 

N je iwo fee ra ojulowo jalamia, baagi, ite ori beedi, iborun atawon eso ara to je oju ni gbese lowo ti ko gara, tete pe won nileese Kemobash Fashion World sori nomba yii:07852697613








No comments:

Post a Comment

Adbox