IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 4 October 2018

ONI LOJOOBI OLOYE SEUN AGBOOLA, E JE KA KI JU U-GBA- MASTER KU ORIIRE

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki egbon wa daadaa,  agba-oje sorosoro, Oloye Seun Agboola ti gbogbo aye mo si Ju u-gba-master ku oriire ojoobi won to waye loni-in.

Adura wa ni pe ki omo olojoobi sopo odun laye ninu ola, owo, alaafia ara ati awon ohun meremere. Igba odun, iseju aaya ni fun
Chief Gbuke Giwa Alaroye. 

No comments:

Post a Comment

Adbox