IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 30 September 2018

O MA SE O: TIRELA WO LU OKO AKERO NI MUSIN,EEYAN MEJI LO KU

Tirela kan to keru lo ti femi- in awon eeyan meji sofo losan yii. 
Gege bi a se gbo, oju ona Agege si Musin, nipinle Eko nijamba yii sele. Lojiji la gbo pe oko ajagbe yii wolu danfo naa, ti dereba oko ati kondokito moto ohun ku lojuese.

Awon ara adugbo yii ni won sare pe awon olopaa, ti won ko je kawon omoota dana sun moto tirela yii,ti won si palemo oku awon eeyan meji to ku naa.

Ohun tawon eeyan tisele yii soju e so fun wa ni pe, ojuona ti ko dara lo fa a ti moto ajagbe naa fi subu lu oko akero yii. 

No comments:

Post a Comment

Adbox