IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 30 September 2018

OMOOBA AJIBOLA HAMMED ELEMORO MU IGBE AYE IRORUN BA AWON EEYAN IBEJU-LEKKI, NI WON BA SO PE OUN NI KO LOO SOJU AWON NILE IGBIMO ASOFIN EKO

OMOOBA AJIBOLA HAMMED ELEMORO, OUN LO KA JUE
LASIKO TON DA FOOMU LATI DIJE PADA 
OMO WA REE O, OUN LO LE E SE E

Ti won ba n so nipa awon ojulowo omo ilu Ibeju-Lekki, to n wa idagbasoke ati ilosiwaju ilu naa, o daju saka pe won ko ni i rin jina rara ti won yoo fi daruko Omooba Ajibola Hammed Elemoro si i, ko si ohun meji to je okunrin naa logun ju bi igbe aye to rorun yoo se de ba onile ati alejo niluu Ibeju-lekki.

Opo eto fun idagbasoke ati aye to nitumo lokunrin naa ti se fawon araalu, lara e ni eto iwosan ofe,oju-ona,ere iadaraya, ere boolu ori papa ati ayo ti ta. Opo awon omo ilu yii ni won ti janfaani eko ati ise latowo Omooba Elemoro. Iyen nikan ko, omoluabi to maa n bowo fun tomode-tagba ni, ki i  koyan awon agba egbe kere ninu egbe oselu APC to ti fee jade.

OGUNLOGO AWON EEYAN NIBI ERE IDARAYA AYO TI OMOOBA ELEMORO SAGBATERU E

Nitori e lawon eeyan ilu Ibeju-Lekki se panupo,ti won fimo-sokan pe Omooba Ajibola Hammed lawon n fe pe ko loo soju awon gege bii asofin lekun idibo Ibeju-Lekki kin in ni, iyen Ibeji-Lekki constituency 1 ninu idibo odun to n bo.


LARA AWON OJU-ONA TI OMOOBA AJIBOLA SE REE
 



 Gbogbo awon omo egbe APC  agba egbe naa ti so pe ko si elomi-in tawon yoo dibo fun lojo ibo abele egbe naa lati je ondije egbe awon to ju Omooba Ajibola Hammed Elemoro lo, nitori pe omo awon ni, o kunju-osuwon, o to gbangba sun loye, o feran awon araalu, bee omo oniluu ti ko ni i fe ko baje ni.

LASIKO ETO IWOSAN OFE TI OMOOBA ELEMORO SE FAWON ARAALU 




MAMA AGBALAGBA YII NAA JANFAANI IWOSAN OFE

Orin kan ti won n ko niluu Ibeju-Lekki bayii ni pe 'Omo wa Ajibola, lo le e se e.   

No comments:

Post a Comment

Adbox