A gbo pe o to ojo meta ti Samson ti n soselu, tawon eeyan ti mo on daadaa nidii e, bo ti fife han lati se asofin lawon eeyan ti n ti i leyin, paapaa awon ara Ibadan, won si ti okunrin naa lokan bale pe oun lawon yoo dibo fun lati soju awon.
Ojutole gbo pe gbogbo ona ti ipo naa yoo fi bo si Samson lowo lo n sa, gbogbo awon to ye ko ri, lo ti ri pata, gbogbo ona to ye ko to, lo ti to.
Ohun kan soso tawon eeyan n duro de bayii ni pe ki egbe APC yan an gege bi eni ti yoo dije loruko egbe won.
No comments:
Post a Comment