IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 14 September 2018

DESOLA, IYAWO KUNLE AFOD PARIWO: ADAGBE-ADAFA TI SU MI LORI OMO MERIN TI MO BI FUN OKO MI




Desola, iyawo Kunle Afod, ti pariwo sita pe o ti sun oun lati ma a da toju awon omo merin to wa laarin oun ati oko oun, o ni kinni ohun ti de gongo emi oun bayii.

Ori eka ayelujara ti won n pe ni 'Istagram' ni Desola gbe oro ohun si pe ko korun foun lati ma a da gbo bukaata awon omo merin to wa laarin oun ati oko oun Afod, emi oun ko gbe kinni ohun mo.

Ohun to so yii lo je kawon eeyan kan so pe boya awon obinrin onitiata ni ko je ki Afod ranti ile mo, to fi da bukaata omokunrin merin sorun iyawo e. Bee lawon mi-in so pe ohun ti Desola se ku die kaato, won ni ohun to se naa ko yato si pe eeyan tu asiiri ile e sita. 

No comments:

Post a Comment

Adbox