Awon omo yahoo mokandinlogun lowo ajo EFCC te ninu ile kan niluu ibadan, nipinle Oyo. Orisirisi oogun abenugongo ati pata awon obinrin ni won ba nile won.
Awon eeyan kan to funra si awon omokunrin yii ni won ta ajo yii lolobo, ti won kolu awon omo yahoo naa lojiji. Gbogbo won pata ni won pale mo lo si ileeese won to wa niluu Ibadan, Lati ibe ni won yoo ti fi oju ba ileejo.
.
No comments:
Post a Comment