IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 5 June 2019

OPE O: IYAWO GBAJUGBAJA AAFA TO TUN N KORIN ALFA MI NI BIMO TUNTUN

Inu idunnu ati ayo ni gbajugbaja aafaa oniwaasi to tun n korin, Khalifa Ismael Aderemi ti gbogbo aye mo si Alfa- mi- ni wa bayii. Ko si ohun to fa idunnu ohun fun okunrinn naa ju omo tuntun ti iyawo e bi laaro oni lo. Gege bi Ojutole se gbo, ileewosan  Omolewa Hospital to wa ni  Gaa Odoota, niluu  ilorin, nipinle Kwara niyawo Alfa-mi-ni bimo si.


Ojutole gbadura pe Olorun yoo wo omo tuntun naa, yoo dagba, yoo soriire.

No comments:

Post a Comment

Adbox