IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 12 January 2021

O ma se o: Olugbenga Kunle Owoade Ti Ku o

Ajalu nla tun ti ja lagboo awon maketa fiimu Yoruba, okan ninu won, Olugbenga Kunle Owoade to ileese Millennium films lo jade

A o mu ekunrere alaye bi iku Okunrin naa se je fun yin

No comments:

Post a Comment

Adbox