IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 21 November 2020

O ma se o: Iya to bi Iyabo Ojo Onitiata ti ku o

Iku ti wole were, o ti mu iya-iya gbajumo osere tiara Yoruba, Iyabo Ojo, iyen Arabinrin Victoria Olubunmi Fatuga leni odun merinlelogota.
Funra Iyabo Ojo lo kede iku mama-mama e yii sori ikanni ayelujara e. O ni ibanuje nla ni iku mama naa je foun, o loun saferi mama yii.


No comments:

Post a Comment

Adbox