IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 21 November 2020

Bi Olorun se ko Dare Melody, gbajumo olorin emin yo ninu ijamba moto ree-Womuwomu ni moto e run



Ti ki i ba se aanu ati oore ofe Olorun, ajalu mi-in ko ba ti sele lagbo awon olorin emi, pelu bi ori se ko yo okan ninu won, Efanjeliisi Dare Onanuga tawon eeyan tun mo si Dare Melody yo ninu ijamba moto to sele si lona Mowe-Ibafo, lojuona marose Ibadan si Eko, ni nnkan bii aago marun-un idaji aaro onii.

Ilu Oyo la gbo pe osere naa ti loo korin sugbon bi won se de Mowe nijamba ohun sele, se ni moto okunrin naa run womuwomu, sugbon Olorun ko je ki enikan kan ba isele naa lo.

Ninu pro Darenibi ti ijamba naa ti sele lo ti wi pe emi mimo so foun lati se adura fun ojo meta, eyi ti oun pari lojo ti ijamba naa sele. Osere yii ni oun dupe lowo Olorun ko seni to ba ijamba naa lo.

No comments:

Post a Comment

Adbox