IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 1 July 2020

Oore-ofe wa fun eeyan meje to ba wa pelu mi lati je ninu oore-ofe ti Olorun fun mi-Ajiyinrere Moty Aduragbemi

Okan gboogi ninu awon olorin emi lorile-ede yii ati loke okun ni Ajiyinrere Oluwatoyin Michelle Aduragbemi ti gbogbo aye mo si Moty, gbajugbaja olorin emi naa ti salaye fun Ojutole pe eeyan meje to ba wa nitosi oun ni yoo lanfaani lati je ninu oore-ofe ti Olorun fun oun gege bii omo ijo sele.

O ni gege bii omo ijo mimo 'Celestial Church of Christ' Olorun foun lebun nla to je pe ebun yoo je anfaani fun eeyan meje ti won ba sun mo oun to fi je pe aburu kankan ko ni i kan awon meje oun, ti won yoo si ri aanu to tayo gba. Moty ni lati kekere loun ti ese oun le oju ona mimo, ti oun ri ara oun sinu ibu eje mimo, ti oun ko si kabaamo lati so fun gbogbo aye pe omo olu ijo mimo loun.


No comments:

Post a Comment

Adbox