IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Sunday, 3 May 2020

Ọpẹ o: Awọn ajinigbe ti fi awọn ibeji Alaaji Akewugbagold silẹ o

Ni nnkan bii aago mẹfa aarọ onii lawọn ajinigbe ti wọn ji awọn ibeji agba oniwaasi to fi ilu Ibadan ṣebugbe, iyẹn Alaaji Taofik Akewugbagold silẹ lẹyin ọsẹ kan ti wọn ji awọn ọmọ naa gbe. Ṣe ni gbogbo awọn ololufẹ ọkunrin naa n ba a dupẹ lọwọ Ọlọru pe o ri awọn ọmọ ẹ yii layọ ati ni alaafia.


No comments:

Post a Comment

Adbox