IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 18 April 2020

Wọn ti sinku Abba Kyari, olori awọn osisẹ Buhari ti arun koronafairọọsi pa

Aarọ yii ni wọn sinku Mallam Abba Kyari olori awọn osisẹ ijọba apapọ to jade laye laaarọ ana. Awọn ẹbi, ọrẹ ati alabasisẹ-pọ ni wọn peju-pesẹ nibi eto isinku naa.

Ṣaaju ki iku too pa oju ọkunrin naa de lẹni ọdun mejilelọgọrin lo ti lugbadi aisan aṣekupani kiakika ti wọn n pe ni koronafairọọsi yii lẹyin to de lati ilu London. Osibitu kan nipinlẹ Eko la gbọ pe Kyari dakẹ si. Ki Ọlọrun rọ awọn ẹbi ẹ loju, ko ba wa ṣẹgun korona kiakia



No comments:

Post a Comment

Adbox