IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 16 July 2019

OPE O: OBA ARA, GBAJUGBAJA OLORIN EMI RA MOTO OLOWO NLA

Inu ayo ati idunnu ni gbajugbaja olorin emi nni, Efanjeliisi Dokita Rotimi Onimole ti gbogbo aye mo si Oba Ara wa bayii. Ohun to fa ayo nla yii ni pe ilu mo on ka olorin omo bibi Isale-Eko naa  sese ra moto toruko re n je 2015 Lexus RX 350. Ojutole gbo pe oko boginni yii ni Oba Ara to tun je onisowo ile ati ile yii fi n jaye ori re kiri igboro bayii.

Gbogbo eni to ba ri Oba Ara, e so fun un pe Ojutole so pe epo wa lowo e, ko je ka ba oun la a o.

No comments:

Post a Comment

Adbox