IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 16 July 2019

OPE O: IYAWO YINKA AYEFELE BI IBETA L'AMERIKA

Iroyin ayo to te wa lowo bayii ni pe iyawo gbajugbaja olorin Yinka Ayefele ti bi ibeta sorile-ede Amerika, okunrin meji, obinrin kan ni won pe awon omo naa.

Akowe iroyin Ayefele, Ogbeni Davis Ajiboye, lo kede iroyin ayo sori ero ayelujara. E o ranti pe ni nnkan bii ose meloo kan seyin lawon eeyan koko ti pariwo pe Yinka Ayefele bi ibeta, sugbon okunrin naa so pe iro nla ni, o ladura lawon eeyan gba foun. 

No comments:

Post a Comment

Adbox