IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 24 July 2019

OPE O: GBAJUGBAJA OLORIN EMI,MEGA 99 DI ASOJU ILEESE NLA

Iroyin ayo to te wa lowo bayii ni pe gbajumo olorin taye n fe, Omooba Abel Dosunmu ti gbogbo aye mo si Mega 99 ti di asoju ileese to maa n ko awon eeyan lo si Jerusalem, ileese nla ti won pe oruko re ni Lammy Trip lokunrin naa soju fun bayii.

Ojutole gbo pe owo nla ni Mega 99 gba lowo ileese yii lati di asoju won, bee ni gbogbo awon to ba darapo mo ileese yii yoo lanfaani lati lo si Jerusalem pelu Mega 99.

No comments:

Post a Comment

Adbox