IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday 12 July 2019

ASIIRI TI ENIKENI KO MO NIPA ILE OLOWO NLA TI LIZZY ANJORIN KO SILU EKO

Loooto ati lododo gbogbo eeyan lo ti gbo pe gbajugbaja osere tiata Yoruba to tun je onisowo pataki nni, Alaaja Aishat Ibunkun ti gbogbo aye mo si Lizzy Anjorin ti pari ile olowo nla to ko silu Eko, koda foto ile nla ohun ti wa lori ero ayelujara, tawon eeyan si ti n ki osere nla naa ku oriire. Sugbon opo ni ko mo pe funra Lizzy tawon ore e tun maa n pe ni Egandogo lo ya pulaani ile yii, oun lo salaye bawon abanikole yoo se ko ile gbaramu ohun. 

Gbogbo alude ati apade bile yii se ri ko seyin e rara.  Awa naa ba osere nla yii dupe lowo Olorun fun oore nla ti Olorun se fun un yii, ile yoo tura,oore mi-in yoo kun un.


No comments:

Post a Comment

Adbox