IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 5 June 2019

Olorun seun: ADUNOLUWA, OMO MOJI OLAIYA KAWE GBOYE NI YUNIFASITI

To ba se pe loooto ni oku ma n boju weyin ni, o  daju inu idunnu nla ni osere tiata Yoruba to doloogbe, Moji Olaiya yoo wa bayii, idi ni pe akobi e, Adunoluwa Farounbi sese kawe gboye ni yunifasiti Babcock to wa ni Ilisan, nipinle Ogun. Ojo keji, osu yii layeye ikekoo-jade naa waye.  Imo nipa ofin ile okere lo se jade.

No comments:

Post a Comment

Adbox