IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 15 June 2019

OLORUN SEUN: AMIRAT OKIKI ABOLORE LORUKO OMO TUNTUN ALFA-MI, GBAJUGBJA AAFAA ONIWAASI TO TUN N KORIN

 Ojo Wesde, ojo kejila, osu yii lawon ebi, ara, ore, ojulumo atawon afenifere peju-pese lati ba gbajugbaja aafaa oniwaasi, to tun n korin, Khalifat Ismael Aderemi ti gbogbo aye mo si Alfa-mi- ni ko omo tuntun ti Olorun fi ta oun ati iyawo e lore jade.
Ile e aafaa oniwaasi naa iyen Alfa-mi-ni Compound to wa ni Khalifa Abusubhanallah, Gaa Odoota, ilu Ilorin layeye ikomojade yii ti waye. Oruko omo tuntun  ni Amirat Okiki Abolore Alfa-mi-ni.
Lara awon eeyan ti won wa nibi ayeye naa ni: Sheik Soibulbayan, Sheik Aribidesi, Sheu Abdulahi Goga,  SheikAtani ati Awoko Arewa. 
Ojutole sadura pe Olorun yoo wo omo yii lawoye, yoo soriire, yoo si lalubarika.









No comments:

Post a Comment

Adbox