IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 13 June 2019

ERO REPETE NIBI ETO ISINKUU DAGUNRO ONITIATA NILUU OSOGBO

Bii omi lawon eeyan ri lagboole Isale-Osun,nilu Osogbo, nipinle Osun,lasiko ti fee sinkuu agba-oje osere tiata Yoruba nni, Alagba Fasasi Olabankewi ti gbogbo aye mo si Dagunro Alakija oogun to jade laye laaaro oni.
Ki won too gbe oku okunrin naa wo ilu Osogbo lati ilu Eko to dake si lawon eeyan ti pe pitimu sadugbo yii,bee lawon ebi ti pese ile ikeyin sile de e,  bi won se gbe oku e de lawon aafaa kirun si i lara, ti ohun gbogbo si di welo, ni nnkan bii aago merin koja ni Dagunro wo kaa ile lo.

Lara awon ilu mo on ka osere to wa nibi eto isinkuu naa ni Murphy Afolabi, toun naa je omo bibi ilu Osogbo. Ojutole gbo pe o to ojo meta ti baba naa ti wa lori akete aisan ko to o di pe olojo de leni aadorin odun.





   

No comments:

Post a Comment

Adbox