IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 4 May 2019

ONI LOJOOBI KABIEESI OWURO LA WA, E JE KA KI OLOYE ABDULKABIR AYINKA ADEWOYE KU ORIIRE

Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki baba wa daadaa, Oloye Abdulkabir Ayinla Adewoye ti gbogbo aye mo si Kabiiesi Owuro la wa ku oriire ayeye ojoobi won to waye loni-in. 

Adura wa ni ki Oloye ilu Esie pe laye daadaa, ki won se opolopo odun laye ninu ola, owo, alaafia ara ati alubarika repete.

No comments:

Post a Comment

Adbox