IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 25 April 2019

WON TI BERE ITOJU BABA SUWE L'AMERIKA

Iroyin ayo to te wa lowo bayii ni pe awon dokita  oyinbo ti bere itoju repete lori aisan to n se gbajugbaja osere tiata Yoruba nni, Alaaji Nurudeen Babatunde Omidina ti gbogbo aye mo si Baba Suwe tabi Adimeru. 

Ileewosan nla kan to wa ni Rhodes Island l'Amerika ni won ti n toju osere omo bibi ilu Ikorodu, nipinle Eko yii.

Adura ti gbogbo awon ololufe Baba Suwe n gba bayii ni pe layo ni yoo pada waa ba awon ni Naijiria, ti yoo pada senu ere tiata to so o di olokiki laarin awon elegbe e.  

No comments:

Post a Comment

Adbox