IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 4 May 2019

MOJI ELEJA, GBAJUMO SOROSORO LO N SOJOOBI, E JE KA KI I KU ORIIRE

A ba okan pataki ninu awon sorosoro radio ati telifisan nni, Moji Ajayi ti gbogbo aye mo si Moji Eleja  ku oriire ayeye ojoobi e to waye loni-in. Ki Olorun je ki omo olojoobi sopo odun laye ninu idera, alaafia ati arisiki to po jaburata.

No comments:

Post a Comment

Adbox