IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Saturday, 4 May 2019

LEYIN TO DAKU FUN WAKATI MERIN, FADEYI OLORO, PARIWO 'MI O KU O, OWO NI MO NILO

Lati bii ojo meji seyin lawon eeyan ti n gbe e kiri pe agba-oje osere tiata Yoruba nni, Ojo Arowosafe tawon eeyan mo si Fadeyi Oloro ti jade laye, tawon eeyan si n beere lowo ara won pe se loooto ni pe Fadeyi Oloro ti ku. 

Sugbon ohun ti a gbo ni pe okunrin naa ti kuro ni ileewosan ijoba to wa ni Agege to wa, o ti pada sile e to wa ni Itele. Gege bi a se gbo, odidi wakati merin ni Fadeyi fi daku, ko too di pe o ji saye pada, ohun to fa a niyen ti won fi n pokiki iku e.

Aisan kindinrin la gbo pe o n yo osere omo bibi ilu Ekiti naa lenu.

No comments:

Post a Comment

Adbox