IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 24 April 2019

BI WON SE FEE FI ORO IKU BABA SUWE SAKOBA FUN PASUMA REE

Oran nla lawon to n lu jibiti lori ero ayelujara fee da si gbajumo osere fuji nni, Alaaji  Wasiu Alabi Pasuma loru, se lawon eeyan naa fee fi oro iku Baba Suwe to gba igboro lenu ojo meta yii ko ba a.

Ohun to sele ni pe se lawon eeyan yii gbe oruko Pasuma ati foto e sori ero ayelujara ti won n pe ni facebook  bii eni pe osere naa ni, oruko e yii lawon onijibiti yii gbe e si pe Baba Suwe ti ku si . Amerika, gbogbo awon eeyan to ri oro yii ni won ti gbagbo loooto ni, ariwo ti gbogbo awon eeyan si n pa ni pe odo Pasuma lawon ti gbo pe Baba Suwe ti ku.  

Won ni osere omo bibi ilu Oro yii lo gbe e sori ero ayelujara pe Baba Suwe ti ku, ohun ti won ko mo ni pe Lagata bawon eeyan se mo osere nla yii si ko ni oruko kankan lori eka ayelujara ti won n pe ni Facebook yii, ise awon onijibiti ni. 

No comments:

Post a Comment

Adbox