IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Wednesday, 17 April 2019

OPE O, IYAWO GALLANT MOPOL TI BIMO O

Inu idunnu ati ayo ni Ogbeni Rilwan Olabiyi, oga ileese to n ba ni seto aabo nibi ayeye, iyen Gallant Mopol wa bayii. Ko si ohun to fa idunnu yii ju omo tuntun tiyawo e sese bimo. Funra okunrin yii lo kede ohun ayo ti Olorun se fun un yii lori ero ayelujara.

Awa naa ba Gallant Mopol dupe lowo Olorun fun oore ayo to se fun un yii, Olorun yoo wo omo naa lawoye. E ku oriire o


No comments:

Post a Comment

Adbox