IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Friday, 12 April 2019

Agba sorosoro, Yomi Ogunlari gbade Oba Owu-Ikosi

Ohun ayo ati idunnu lo n sele lowo niluu Owu-Ikosi, legbee ilu Agbowa, nipinle Eko bayii. Ko si ohun to fa eyi ju ade ti oba ilu naa, Oba Nelson Abayomi Aderemi Ogunlari gba leyin odun meji ti won ti yan agba sorosoro to maa n seto Eweso lori radio Radio Lagos gege bii oba ilu naa .





Ojutole gbo pe gbogbo eto ti won se fun oba alaye ni won ti se fun oba tuntun yii. Beeyan ba wo ilu naa bayii,
yoo mo pe nnkan ayo kan lo sele si won niluu yii. Ojutole naa gbadura fun oba wa pe kade pe lori, ki bata pe lese, kesin oba jeko pe.

No comments:

Post a Comment

Adbox