IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Thursday, 18 April 2019

OPE O, GBAJUMO SOROSORO, IDRIS SHOGBOLA DI OTUNBAALE ILU ARIJELORO

Oni-in, Ojobo, Tosde ni jawe oye le okan ninu awon sorosoro ori radio, to tun je akowe ipolongo egbe FIBAN nipinle Eko, Idris Shogbola ti gbogbo aye mo si Eniyan lori gege bii Otunbaale ilu Ajijeloro. Wamuwamu lawon ebi, ara ati ore pejo lasiko ti won jawe oye le baba oloye tuntun naa lori.

Ojo Abameta, Satide to n bo yii ni faaji nla yoo san, ti ariya repete yoo waye lori oye tuntun yii. Gbogbo wa pata nileese Ojutole la ki baba oloye tuntun pe ewe oye a a mori o







No comments:

Post a Comment

Adbox