Gbajumo osere tiata Yoruba nni, Eniola Badmus, ti pariwo sita pe oun ko mo ese toun se awon eeyan ti won fi n ro iku ro oun. Osan yii losere to sanra daadaa kigbe sita pe oun ko ku o, kawon eeyan sinmi ati ma a pokiki iku oun. Pelu ogbe okan lobinrin yii fi beere pe ese wo loun se awon eeyan gan-an ti won ko fi fe koun gbe aye.
Ko si ohun to fa oro ti Eniola so ju ariwo iku e to gba igboro lati bii ojo meta seyin lo, paapaa, lori ero ayelujara, se ni won gbe foto ibi ti osere naa ti wa lori beedi pelu ogbe lara sori ero to kari aye yii.
Alaye ti Eniola, ti won tun mo si Wule Bantu tabi Gbogbo Biz girls se ni pe inu fiimu oun kan ti ko ti i jade loun ti ya foto ti won n gbe kiri yii.
Ju gbogbo e lo, Eniola ti so pe oun ko ku o, ki won pariwo iku oun kiri.
Wednesday, 10 April 2019
KI LODE TAWON EEYAN FEE PA MI, ENIOLA BADMUS ONITIATA PARIWO
Tags
# LAGBO OSERE
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
LAGBO OSERE
Tags
LAGBO OSERE
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment