IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Tuesday, 23 April 2019

IRO NI O, BABA SUWE KO KU O,IYAWO E LO SO BEE

Lati bii wakati merin seyin lariwo naa ti n lo laarin ilu pe gbajumo osere tiata Yoruba nni, Alaaji Nurudeen Babatunde Omidina ti gbogbo aye mo si Baba Suwe ti ku. Okiki ohun kan debii pe awon eeyan n beere lowo wa lati mo boya loooto ni Adimeru ti jade laye.

Nitori e la se pe nomba foonu e, iyawo e to gbe e lo fi wa lokan bale pe ko si kinni kan to se okunrin naa, o ni orile-ede Amerika ni Baba Suwe to n gba itoju.

'Ojutole, e ma da won lohun jare, ko si kinni kan to se Baba Suwe, e ma teti si ariwo tawon eeyan kan n pa'.

No comments:

Post a Comment

Adbox