Lati aaro ana lariwo naa ti n lo laarin ilu pe gbajumo osere
tiata Yoruba nni, Alaaji Nurudeen Babatunde Omidina ti gbogbo aye mo si
Baba Suwe ti ku. Okiki ohun kan debii pe awon eeyan n beere lowo wa lati
mo boya loooto ni Adimeru ti jade laye.
Nitori e
la se pe nomba foonu e, iyawo e, Bola Omidina to gbe e lo fi wa lokan bale pe ko si
kinni kan to se okunrin naa, o ni orile-ede Amerika ni Baba Suwe to n
gba itoju.
'Ojutole, e ma da won lohun jare, ko si kinni kan to se Baba Suwe, e ma teti si ariwo tawon eeyan kan n pa'.
Wednesday, 24 April 2019
IKA LAWON TO SO PE BABA SUWE TI KU-BOLA,IYAWO E
Tags
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment